Text Results

Tune Identifier:"^trust_and_obey_towner$"
In:texts

Planning worship? Check out our sister site, ZeteoSearch.org, for 20+ additional resources related to your search.
Showing 21 - 23 of 23Results Per Page: 102050
TextAudio

Sa Gbekele

Author: John H. Sammis; Anonymous Appears in 1 hymnal First Line: Gba t’a b’Oluwarin ninu ‘mole oro re Refrain First Line: Sa gbekele, ona miran kosi Lyrics: 1 Gba t’a b’Oluwarin ninu ‘mole oro re, Ona wa yio ti ma mole to! Gba t’a ban se’fe Re, on y’o ma ba wa gbe, At’ awon t’o ba gbeke won le. Egbe: Sa gbekele, ona miran kosi Lati layo n’nu Jesu, jupe k’a gbekele. 2 Ko s’ohun to le de, loke tabi nile Tole ko agbara re l’oju; Iyemeji a’teru, ibanuje, ekun Kole duro b’a ba gbekele. [Egbe] 3 Ko s’eru t’ale ru, ko s’aro t’a le pin Ti ki y’o san ere re fun wa Kosi arokan mo, tabi ifajuro Sugbon ibukun b’aba gbekele. [Egbe] 4 A ko le f’enu so b’ife re ti po to Titi a o f’ara wa rubo Aanu ti o nfihan, at’ayo t’o nfun ni Je t’awon to ba gbeke won le. [Egbe] 5 Nibi ‘pade ayo ka joko ni ese Re. Tabi kajo rin ni ona Re. Oun to so la o se, ibi to wu la o lo; Kosi beru, ka sa gbekele. [Egbe] Used With Tune: [Gba t’a b’Oluwarin ninu ‘mole oro re]
Page scans

Folgen und traun

Appears in 1 hymnal First Line: Wenn wir wandeln in Herrn Refrain First Line: Folg' und vertrau auf Jesum und schau Used With Tune: [Wenn wir wandeln in Herrn]

Trust and obey

Author: Rev. J. H. Sammis Appears in 5 hymnals Used With Tune: [Trust and obey]

Pages


Export as CSV
It looks like you are using an ad-blocker. Ad revenue helps keep us running. Please consider white-listing Hymnary.org or getting Hymnary Pro to eliminate ads entirely and help support Hymnary.org.