Choose a text to compare against: | Compare to:These texts are sorted by similarity. Texts in green are more similar to the current text, and red ones are more different. |
1 Iranse Oluwa! E duro nid’ ise; E toju oro Re mimo, E ma sona Re sa. 2 Je k’ imole nyin tan, E tun fitila se; E damure girigiri, Oruko Re l’ eru. 3 Sora! l’ ase Jesu, B’a ti nse ko jina B’o ba kuku ti kan ’lekun Ki e si fun logan. 4 Iranse ’re l ’eni Ti a ba nipo yi; Ayo l ’ on o fi r’ Oluwa Y’o f’ ola de l’ ade. 5 Kristi tikalare Y’o te tabili fun Y’o gb’ ori iranse na ga Larin egbe Angel. | The Cyber Hymnal #15883 |