15909. Wa Eyin Olooto

1 Wa eyin olooto, Layo at’ isegun,
Wa ka lo, wa ka lo si Betlehem,
Wa ka lo wo o! Oba awon Angeli.

Egbe:
E wa ka lo juba Re,
Ewa ka lo juba Re,
E wa ka lo juba
Kriti Oluwa.

2 Olodumare ni, Imole ododo,
Kosi korira inu Wundia;
Olorun paapaa ni, Ti a bi, ti a ko da. [Egbe]

3 Angeli e korin, Korin itoye re;
Ki gbogbo eda orun si gberin:
Ogo f’Olorun Li oke orun. [Egbe]

4 Ni tooto, a wole, F’Oba t’a bi loni;
Jesu iwo l’a wa nfi ogo fun:
’Wo omo Baba, To gba’ra wa wo. [Egbe]

Text Information
First Line: Wa eyin olooto, Layo at’ isegun
Title: Wa Eyin Olooto
English Title: O come, all ye faithful, joyful and triumphant
Translator: Anonymous
Refrain First Line: E wa ka lo juba Re
Language: Yoruba
Copyright: Public Domain
Tune Information
Name: [Wa eyin olooto, Layo at’ isegun]
Composer: John F. Wade
Key: G Major or modal
Copyright: Public Domain



Media
MIDI file: MIDI
More media are available on the tune authority page.

Suggestions or corrections? Contact us