| 15906 | The Cyber Hymnal#15907 | 15908 |
| Text: | Ore Wo L'aini Bi Jesu |
| Author: | Joseph M. Scriven |
| Translator: | Anonymous |
| Tune: | ERIE |
| Composer: | Charles Crozat Converse |
| Media: | MIDI file |
1 Ore wo l’ani bi Jesu, ti o ru banuje wa!
Anfani wo lo po bayi lati ma gbadura si!
Alafia pupo l’a nsonu, a si ti je rora po,
Tori a ko fi gbogbo nkan s’adura niwaju re.
2 Idanwo ha wa fun wa bi? A ha nni wahala bi?
A ko gbodo so ’reti nu; sa gbadura si Oluwa.
Ko s’oloto orebi re ti ole ba wa daro,
Jesu ti mo ailera wa; sa gbadura s’Oluwa.
3 Eru ha nwo wa l’orun bi, aniyan ha po fun wa?
Olugbala je abo wa, sa gbadura s’Oluwa.
Awon ore ha sa o ti? Sa gbadura s’Oluwa.
| Text Information | |
|---|---|
| First Line: | Ore wo l’ani bi Jesu, ti o ru banuje wa! |
| Title: | Ore Wo L'aini Bi Jesu |
| English Title: | What a friend we have in Jesus |
| Author: | Joseph M. Scriven |
| Translator: | Anonymous |
| Meter: | 87.87 D |
| Language: | Yoruba |
| Copyright: | Public Domain |
| Tune Information | |
|---|---|
| Name: | ERIE |
| Composer: | Charles Crozat Converse (1868) |
| Meter: | 87.87 D |
| Key: | F Major or modal |
| Copyright: | Public Domain |
| Media | |
|---|---|
| Adobe Acrobat image: | |
| MIDI file: | |
| Noteworthy Composer score: | |