| 15901 | The Cyber Hymnal#15902 | 15903 |
| Text: | Ojo Ibukun, Y'o Si Ro |
| Author: | Daniel W. Whittle |
| Translator: | Anonymous |
| Tune: | [Ojo ibukun y’o si ro] |
| Composer: | James McGranahan |
| Media: | MIDI file |
1 "Ojo ibukun y’o si ro!"
Eyi n’ileri ife;
A o ni itura didun
Lat’ odo Olugbala.
Egbe:
Ojo ibukun! Ojo ibukub l’a n fe
Iri anu wa yi wa ka, sugbon ojo l’a ntoro
2 "Ojo ibukun y’o si ro!"
Isoji iyebiye;
Lori oke on petele
Iro opo ojo m bo. [Egbe]
3 "Ojo ibukun y’o si ro!"
Ran won si wa Oluwa!
Fun wa ni itura didun
Wa, f’ola fun oro Re. [Egbe]
4 "Ojo ibukun y’o si ro!"
Nwon ’ba je le wa loni!
B’a ti njewo f’Olorun wa
T’a n pe oruko Jesu. [Egbe]
| Text Information | |
|---|---|
| First Line: | Ojo ibukun y’o si ro! |
| Title: | Ojo Ibukun, Y'o Si Ro |
| English Title: | There shall be showers of blessing |
| Author: | Daniel W. Whittle |
| Translator: | Anonymous |
| Refrain First Line: | Ojo ibukun! Ojo ibukub l’a n fe |
| Language: | Yoruba |
| Copyright: | Public Domain |
| Tune Information | |
|---|---|
| Name: | [Ojo ibukun y’o si ro] |
| Composer: | James McGranahan |
| Key: | B♭ Major |
| Copyright: | Public Domain |