Please give today to support Hymnary.org during one of only two fund drives we run each year. Each month, Hymnary serves more than 1 million users from around the globe, thanks to the generous support of people like you, and we are so grateful.

Tax-deductible donations can be made securely online using this link.

Alternatively, you may write a check to CCEL and mail it to:
Christian Classics Ethereal Library, 3201 Burton SE, Grand Rapids, MI 49546

15908. Sa Gbekele

1 Gba t’a b’Oluwarin ninu ‘mole oro re,
Ona wa yio ti ma mole to!
Gba t’a ban se’fe Re, on y’o ma ba wa gbe,
At’ awon t’o ba gbeke won le.

Egbe:
Sa gbekele, ona miran kosi
Lati layo n’nu Jesu, jupe k’a gbekele.

2 Ko s’ohun to le de, loke tabi nile
Tole ko agbara re l’oju;
Iyemeji a’teru, ibanuje, ekun
Kole duro b’a ba gbekele. [Egbe]

3 Ko s’eru t’ale ru, ko s’aro t’a le pin
Ti ki y’o san ere re fun wa
Kosi arokan mo, tabi ifajuro
Sugbon ibukun b’aba gbekele. [Egbe]

4 A ko le f’enu so b’ife re ti po to
Titi a o f’ara wa rubo
Aanu ti o nfihan, at’ayo t’o nfun ni
Je t’awon to ba gbeke won le. [Egbe]

5 Nibi ‘pade ayo ka joko ni ese Re.
Tabi kajo rin ni ona Re.
Oun to so la o se, ibi to wu la o lo;
Kosi beru, ka sa gbekele. [Egbe]

Text Information
First Line: Gba t’a b’Oluwarin ninu ‘mole oro re
Title: Sa Gbekele
English Title: When we walk with the Lord in the light of his word
Author: John H. Sammis
Translator: Anonymous
Refrain First Line: Sa gbekele, ona miran kosi
Language: Yoruba
Copyright: Public Domain
Tune Information
Name: [Gba t’a b’Oluwarin ninu ‘mole oro re]
Composer: Daniel B. Towner
Key: F Major or modal
Copyright: Public Domain



Media
MIDI file: MIDI
More media are available on the tune authority page.

Suggestions or corrections? Contact us
It looks like you are using an ad-blocker. Ad revenue helps keep us running. Please consider white-listing Hymnary.org or getting Hymnary Pro to eliminate ads entirely and help support Hymnary.org.