15907. Ore Wo L'aini Bi Jesu

1 Ore wo l’ani bi Jesu, ti o ru banuje wa!
Anfani wo lo po bayi lati ma gbadura si!
Alafia pupo l’a nsonu, a si ti je rora po,
Tori a ko fi gbogbo nkan s’adura niwaju re.

2 Idanwo ha wa fun wa bi? A ha nni wahala bi?
A ko gbodo so ’reti nu; sa gbadura si Oluwa.
Ko s’oloto orebi re ti ole ba wa daro,
Jesu ti mo ailera wa; sa gbadura s’Oluwa.

3 Eru ha nwo wa l’orun bi, aniyan ha po fun wa?
Olugbala je abo wa, sa gbadura s’Oluwa.
Awon ore ha sa o ti? Sa gbadura s’Oluwa.

Text Information
First Line: Ore wo l’ani bi Jesu, ti o ru banuje wa!
Title: Ore Wo L'aini Bi Jesu
English Title: What a friend we have in Jesus
Author: Joseph M. Scriven
Translator: Anonymous
Meter: 87.87 D
Language: Yoruba
Copyright: Public Domain
Tune Information
Name: ERIE
Composer: Charles Crozat Converse (1868)
Meter: 87.87 D
Key: F Major or modal
Copyright: Public Domain



Media
Adobe Acrobat image: PDF
MIDI file: MIDI
Noteworthy Composer score: Noteworthy Composer Score
More media are available on the tune authority page.

Suggestions or corrections? Contact us